Podcasts by Ìtànkálè Ìhìnrere

Ìtànkálè Ìhìnrere

Ètò yí wà fún gbogbo onígbàgbọ́ nínú Jésù Krístì tó ní ìfẹ́ láti mú ìyípadà rere bá gbogbo ènìyàn tí ó wà ní gbogbo Orílẹ̀-Èdè àgbáyé. Eto yi yoo maa ru o soke, yi o si maa ko o ni eko lati le mu iyipada wa si aye yi. O ma ko bi o ti ma lo agbara Olorun ati Oro Olorun ninu aye re so Awon Eniyan da omo leyin Kristi. Ti won yo si ma ni iyipada aye won si igbala ati iyipada aye won si igbe-aye Ayo, Alaafia ati Ireti.

Further podcasts by Victor O. OlaJesu

Podcast on the topic Christentum

All episodes

Ìtànkálè Ìhìnrere
Ipe Meta ti Kristi Pe Gbogbo Onigbagbo from 2020-08-11T02:32:31

Awon ipe Meta ti o gbodo dahun lati je omo eyin Kristi tooto. Maku 1:17.

Listen
Ìtànkálè Ìhìnrere
Kristi Fun Gbogbo Aye Nisisiyi from 2020-08-10T09:39:28

Bawo ni Gbogbo egbelegbe Eniyan ni agbaye yo se di omo-leyin Kristi?

Listen